Useful phrases in Yoruba

A collection of useful phrases in Yoruba, a Niger-Congo language spoken in Nigeria, Benin, Togo and a number of other countries.

To see these phrases in many other languages click on the English versions.

English Yorùbá
Welcome Ẹ ku abọ
Hello
(General greeting)
Ẹ n lẹ
How are you? ̣Se daadaa ni o wa?
Reply to 'How are you?' Mo wa daadaa, o ̣se. Iwọ naa n kọ?
Long time no see O to ọjọ mẹta o
O pẹ ti a ri ara wa o
What's your name? Ki ni orukọ rẹ?
My name is ... Orukọ mi ni……
Where are you from? Nibo ni o ti wa?
I'm from ... Mo wa lati ...
Pleased to meet you Inu mi dun lati mọ ọ
Good morning
(Morning greeting)
Ẹ ku aarọ
Good afternoon
(Afternoon greeting)
Ẹ ku ọsan
Good evening
(Evening greeting)
Ẹ ku alẹ
Good night O da aarọ
Goodbye
(Parting phrases)
O da abọ
Good luck Yoo dara o
Yoo bọ si o
Cheers!
(Toasts used when drinking)
Ayọ ni o
Kara o le
Have a nice day Oni a dara o
Bon appetit /
Have a nice meal
Ounjẹ ajẹye o
Yoo gba ibi re
Bon voyage /
Have a good journey
O da abọ
Ka sọ layọ o
I understand O ye mi
I don't understand Ko ye emi
Yes Bẹẹ ni
No Bẹẹ kọ
Ó ti
Ra ra
Maybe Boya
I don't know N ko mo
Please speak more slowly Jọwọ, rọra maa sọrọ
Please say that again Jọwọ, tun un sọ
Please write it down Jọwọ, kọ ọ silẹ
Do you speak English? Ṣe o le sọ èdè oyinbo?
Do you speak Yoruba? ̣Se o n sọ Yorùbá?
Yes, a little
(reply to 'Do you speak ...?')
Bẹẹ ni, diẹ
How do you say ... in Yoruba? Bawo ni o se le sọ …... ni Yorùbá
Excuse me Ẹ ̣se fun mi
Ẹ jọwọ, ẹ gbọ mi
How much is this? Eelo ni eyi?
Sorry Pẹlẹ
Thank you O ̣se
E se
Reply to thank you Ko to ọpẹ
Where's the toilet? Nibo ni ile igbọnsẹ wa?
This gentleman will pay for everything Alagba yii yoo sanwo fun gbogbo rẹ
This lady will pay for everything Iyaafin yii yoo sanwo fun gbogbo rẹ
Would you like to dance with me? ̣Se iwọ maa ba mi jo?
I miss you Aro re so mi
I love you Mo nifẹẹ rẹ
Get well soon Da ara ya o
Leave me alone! Fi mi silẹ
Help! Ẹ gba mi o!
Fire! Ina o!
Stop! Duro nbẹ!
Call the police! Pe awọn ọlọpaa
Christmas and New Year greetings Ẹ ku Ayọ Keresimesi ati Ọdun Tuntun
Easter greetings Ẹ ku Ayọ Ajinde
Birthday greetings Ẹ ku Ayọ Ọjọ Ibi
One language is never enough Ede kan ko to ri rara
My hovercraft is full of eels
Why this phrase?
Ọkọ afategun-sare mi kun fun ẹja arọ

Yoruba phrases provided by Adedamola Olofa

Information about Yoruba | Useful phrases in Yoruba | Tower of Babel in Yoruba | Yoruba learning materials

Links

Other collections of Yoruba phrases
http://www.motherlandnigeria.com/languages.html
http://www.abeokuta.org/yoruba.htm

Phrases in Niger-Congo languages

Ewe, Igbo, Kinyarwanda, Lozi, Ndebele (Northern), Northern Sotho, Sesotho, Shona, Swahili, Tsonga, Tswana, Tumbuka, Umbundu, Wolof, Xhosa, Yorùbá, Zulu

Phrases in other languages


TranslateZilla.com Free Translation Online | stepcalculator.com | Essayshark | Paper Writing Service | Аспирация

Have you ever dreamed of becoming a person who knows all the languages of the world and can effortlessly speak with anyone and anywhere on their native tongue? It's probably impossible but you can, at least, try to learn some of the most common phrases. We have a very helpful table here with popular phrases you might need while traveling and learning the languages.

All you have to do is to click on the word you're interested in and you'll see its translation to many languages. Have fun learning and exploring the world!

Translate English to Chinese | Translate English to Dutch | Translate English to French | Translate English to German | Translate English to Italian | Translate English to Portuguese | Translate English to Spanish